< meta name =" googlebot - news " content =" index, follow , max - image- preview : large, max- snippet : - 1 , max - video- preview : - 1 ">  
Login Register
Share On↷
Pinterest | LinkedIn | Flipboard
Get full access to #That-cruise.net.ng Use the app

Top 21 “Juju-Charms Man And Woman Need to Survive After Prayer » That-cruise

ADVERTISEMENT

Top 21 “Juju-Charms Man And Woman Need to Survive After Prayer

man power by juju class

×Delete| Set As PPix| Edit Article| Share
man power Story By juju class



This are the list of jasz or let say charm that can also help you spiritually you need this to make you life journey brighter and easy moving read juju's below!!

1, TI ISE EEYAN BA DARU:- ODIDI ALAKAN KAN TI KO KAN NI IBIKANKAN, ESURU GUDUGUDU, AO GUN GBOGBO RE PAPO, AOPO MOSE DUDU, AO MO FIWE.



2, TURARE AWON AGBA TAFI RI OJU RERE WON:- EWE AGUNMONA ARA OPE ATI TI ARA IGI, EBO OBO , WERENJEJE, IMI OORUN, EGBO EGBESI, KORIKO TOHU LORI SAARE OKU, ATA WERE IJOSI, AOGUN PAPO AO MO BU SINU INA NI ALALE JIMOH.

3, OGUN TAFI WE OJU EGBO OLOJO PI PE:- AFOMO ARA IGAN NA, ODIDI ATARE KAN, AOJO PAPO MO BU LOJU EGBO NA.
ADVERTISEMENT
4, IPESE OLA:-- EIYE ALAPANDEDE, ATARE AAJA KAN, AOJO PAPO AORO SINU ADO IDE AOMO BU LORI ESE , OWO KO GBODO KAN O.
DOWNLOAD MP3

5, EYONU AIYE:- EKOLO IDI IKOKO, EPO OBO, AOLOPO AOFI SIN GBERE SORUN OWO MEJEJI, TI OBA DI OJO KETA , AO PO IYOKU MO OSE AOFI EPO PUPA PO AO MO FI WE.

6, OGUN TI AFI WE IBI DANU:-- IKAN TI OBA PON SORI IYA RE, ILA TI OBA KO SORI IYA RE, ATA IJOSI EYO MEJE(7), IYO ISEBE , AOGUN GBOGBO PO,AOPO MO OSE DUDU AOLO MO FI WE SI ODO TI O NSAN. OFORE:- EEGUN KIMU ILA KI ILA MOLE KO, EEGUN KI MU IKAN KIKAN MOLE WO EWU EJE, EEGUN KIMU ATA KI ATA MOLE TA ENU, EEGUN KI MU IYO KIYO MOLE DUN OBE, GBOGBO EEGUN AIYE MI KO PARE.
ADVERTISEMENT
7, IMULE AGBA:-- YIMIYIMI TI OBA NYI IMI LO LOJU ONA, AOFI OWO OTUN JA EWE KAN LOWO OTUN , AO TUN FI OWO OSI JA EWE KAN LOWO OSI, AOPA MEJEJI PO, AOFI MU OHUN ATI IMI TI O NYI LO, AOJO PELU PADI ATARE KAN, AORO SINU ADO , AO JU ADO NA SINU AGBADA AOTUN JO , AO WA RO SINU ADO MIRAN , AOFI AWO FUNFUN RAN NI IKORUN
ADVERTISEMENT
8, ATOSI:-- EPA IKUN, EGBO AKO IBEPE, OPON OYINBO, BARA, KANHUNBILALA, AOGUN PAPO AOFUN OMI RE FUN MUMU.

9, EBE AGBA:- ORI AJA, ORI ELEDE, ODINDI BIBLE TABI QURAN KAN, EWE OORI LOPOLOPO, AOJO PAPO AORO SINU SERE AO MO FI FO EKO TUTU MU.

10, ASETA:- IYE AGBE 3, IYE ALUKO 3, IKO- ODE 3, IKUKU EKUN, AOYO EKANNA RE AOWA TOJU EGUNGUN EKUN, EGUNGUN IKOKO, ATI AWO WON DIE DIE , AORE FUNFUN ISU TANGIRI AOLO MO , AO WA GUN GBOGBO RE PAPO, AOPO MO OSE AOKO SINU PAKO, AOFI LE OKE AOMO BU WE.
ADVERTISEMENT
11, OHUNMO:- ORI IGUN KAN TI OJU RE PE, ORI AKALA KAN TI OJU RE PE, ORI ELULU TI OJU RE PE, ORI OLONGBO TI OJU RE PE, PADI ATARE KAN, AO JO GBOGBO RE PAPO, AO MO FI FOKO MU.

12, AWURE OJA TODAJU:- BINTU LOFINDA 2, KAFURA 2, EKU ASIN KAN, ORI OKA 2, AOGUN PAPO, AOPO MO OSE DUDU, AO FI WE NI OJO KERIN KERIN.

13, EDA:_ PANUMO ABO, PANUMO ABAFE, PATANMO, IRU KERE AGBADO AOYO TI YIO PO DARADARA, AOJO PADI ATARE KAN MO, OBINRIN YIO MO FI FOKO MU.

14, AFOSE TODAJU:- OROGBO KAN, OBI ABATA OLOJU 4, KAN, AOSUN OBI YI JONA DARADARA ATI OROGBO NA, ORONRO OBUKO KAN, OMI ISE OKU LAOFI PO AOKO SINU AGOGO IDE KAN.
ADVERTISEMENT
ERO:- TI ABA LO TAN( ODUNDUN, TETE ABALAYE, EWE RINRIN, AOLOPO AO AOMO LA.

15, OGUN IDAKOLE TI NKAN OMO OKUNRIN BA KERE JU OJO ORI LO:- OKA BABA FUNFUN, KANHUNBILALA, OKUTA AKO FUNFUN, ODIDI ATARE KAN, AOBO EPO ATARE KURO, EGBO AKOGUN DIE, AOLO GBOGBO RE PO YIO KUNNA DARADARA, AO FIFO MU EKO TUTU.

16, OGUN OJU DIDUN:_ ORI LILI, ODIDI ATARE KAN, AOJO AOLO YIO KUNNA, AODA MO TIRO YIO MO LE SOJU NA.

17, EYONU AIYE:- AFARA OYIN, EWE OWO, EWE AGBAYUN, ODIDI ATARE KAN, AOJO PAPO AOLO SUGAR MO ,AOMO BUSI OWO , AO MO LA AOMO FI OMI Si

18, ADODUN TI AFI GBA TI OWO OBINRIN:- OGAN TI OYO SOJU ONA AOGE TI YIO PO DARADARA, AOGUN PO MO OSE IYEKIYE, AOMO FI FO OKO.

19, ISOYE:- EWE OSUSU, IYO, ATA ,EPO, AOLOPO AOFI SE EJA ABORI JE.
ADVERTISEMENT
20, OGUN ALEKO TI OKO FI LE DADA:- OMUNU ASUNWON GIDI, KANHUNBILALA, ETU IBON, AOLOPO AMA FI MU EKO GBIGBONA.

21, ISOYE :- ORI OKERE, IKO-ODIDERE KAN, AOFI HA OKERE LENU, OKO ATARE KAN, SI SO ORI EKO DIE, AOJO PAPO, AOLOPO DARADARA, AO HANTA YASIN SINU IKE OLOMORI KAN, AO MO FI LO OGUN NA. TEMI TIYIN TOTO.

https://hypesloaded.top/Download-our-apps





WATCH ON YOUTUBE BELOW;


Top 21 “Juju-Charms Man And Woman Need to Survive After Prayer » Hottest » Story’s » Trending
# juju # man power #class Exclusive @ Hypesloaded

Do you want to be notified of new song releases? Click to follow us on Facebook now!


 

Do you find THATCRUISE useful? Click here to give us five stars rating!

More

Tags

 

Join the Discussion

anonymous comment avatar Anonymous
Hmm.. Super Cool Reply
5 days ago


No one has commented yet. @This Hour Kindly Be The First! @This Hour !! and Earn Money On Hypesloaded

Leave a Reply


Write A Comment Below
please add comments on This Articles Top 21 “Juju-Charms Man And Woman Need to Survive After Prayer